Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Maeda Ayahs #38 Translated in Yoruba

إِلَّا الَّذِينَ تَابُوا مِنْ قَبْلِ أَنْ تَقْدِرُوا عَلَيْهِمْ ۖ فَاعْلَمُوا أَنَّ اللَّهَ غَفُورٌ رَحِيمٌ
Ayafi awon t’o ronu piwada siwaju ki e to lagbara lori won. Nitori naa, e mo pe dajudaju Allahu ni Alaforijin, Asake-orun
يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا اتَّقُوا اللَّهَ وَابْتَغُوا إِلَيْهِ الْوَسِيلَةَ وَجَاهِدُوا فِي سَبِيلِهِ لَعَلَّكُمْ تُفْلِحُونَ
Eyin ti e gbagbo ni ododo, e beru Allahu, ki e si wa ategun si odo Re (pelu ise rere). E jagun fun esin Re nitori ki e le jere
إِنَّ الَّذِينَ كَفَرُوا لَوْ أَنَّ لَهُمْ مَا فِي الْأَرْضِ جَمِيعًا وَمِثْلَهُ مَعَهُ لِيَفْتَدُوا بِهِ مِنْ عَذَابِ يَوْمِ الْقِيَامَةِ مَا تُقُبِّلَ مِنْهُمْ ۖ وَلَهُمْ عَذَابٌ أَلِيمٌ
Dajudaju awon t’o sai gbagbo, ti o ba je pe gbogbo ohun ti n be lori ile aye patapata je tiwon ati iru re pelu re lati fi gba ara won sile nibi iya Ojo Ajinde, A o nii gba a ni owo won. Iya eleta-elero si wa fun won
يُرِيدُونَ أَنْ يَخْرُجُوا مِنَ النَّارِ وَمَا هُمْ بِخَارِجِينَ مِنْهَا ۖ وَلَهُمْ عَذَابٌ مُقِيمٌ
Won yoo fe jade kuro ninu Ina, won ko si nii le jade kuro ninu re. Iya gbere si wa fun won
وَالسَّارِقُ وَالسَّارِقَةُ فَاقْطَعُوا أَيْدِيَهُمَا جَزَاءً بِمَا كَسَبَا نَكَالًا مِنَ اللَّهِ ۗ وَاللَّهُ عَزِيزٌ حَكِيمٌ
Ole lokunrin ati ole lobinrin, e ge owo awon mejeeji. (O je) esan fun ise owo awon mejeeji. (O si je) ijiya lati odo Allahu. Allahu si ni Alagbara, Ologbon

Choose other languages: