Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Lail Ayahs #20 Translated in Yoruba

الَّذِي كَذَّبَ وَتَوَلَّىٰ
eni ti o pe ododo niro, ti o si keyin si i
وَسَيُجَنَّبُهَا الْأَتْقَى
Won si maa gbe (Ina) jinna si oluberu (Allahu)
الَّذِي يُؤْتِي مَالَهُ يَتَزَكَّىٰ
eni t’o n fi dukia re tore, ti o n safomo (re)
وَمَا لِأَحَدٍ عِنْدَهُ مِنْ نِعْمَةٍ تُجْزَىٰ
Ko si si oore idera kan ti (o ni lokan) lati gba ni esan ni odo enikeni
إِلَّا ابْتِغَاءَ وَجْهِ رَبِّهِ الْأَعْلَىٰ
bi ko se pe lati fi wa oju rere Oluwa re, Eni Giga julo

Choose other languages: