Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Baqara Ayahs #12 Translated in Yoruba

2:8
وَمِنَ النَّاسِ مَنْ يَقُولُ آمَنَّا بِاللَّهِ وَبِالْيَوْمِ الْآخِرِ وَمَا هُمْ بِمُؤْمِنِينَ
O si n be ninu awon eniyan, eni t’o n wi pe: “A gbagbo ninu Allahu ati Ojo Ikeyin.” Won ki i si se onigbagbo ododo
2:9
يُخَادِعُونَ اللَّهَ وَالَّذِينَ آمَنُوا وَمَا يَخْدَعُونَ إِلَّا أَنْفُسَهُمْ وَمَا يَشْعُرُونَ
Won n tan Allahu ati awon t’o gbagbo ni ododo je. Won ko si le tan eni kan je bi ko se emi ara won; won ko si fura
فِي قُلُوبِهِمْ مَرَضٌ فَزَادَهُمُ اللَّهُ مَرَضًا ۖ وَلَهُمْ عَذَابٌ أَلِيمٌ بِمَا كَانُوا يَكْذِبُونَ
Arun kan wa ninu okan won, nitori naa Allahu se alekun arun fun won. Iya eleta-elero si wa fun won nitori pe won n paro
وَإِذَا قِيلَ لَهُمْ لَا تُفْسِدُوا فِي الْأَرْضِ قَالُوا إِنَّمَا نَحْنُ مُصْلِحُونَ
Nigba ti won ba so fun won pe: “E ma sebaje lori ile.” Won a wi pe: “Awa ni alatun-unse.”
أَلَا إِنَّهُمْ هُمُ الْمُفْسِدُونَ وَلَٰكِنْ لَا يَشْعُرُونَ
E kiye si i! Dajudaju awon gan-an ni obileje, sugbon won ko fura

Choose other languages: