Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Baqara Ayahs #72 Translated in Yoruba

قَالُوا ادْعُ لَنَا رَبَّكَ يُبَيِّنْ لَنَا مَا هِيَ ۚ قَالَ إِنَّهُ يَقُولُ إِنَّهَا بَقَرَةٌ لَا فَارِضٌ وَلَا بِكْرٌ عَوَانٌ بَيْنَ ذَٰلِكَ ۖ فَافْعَلُوا مَا تُؤْمَرُونَ
Won wi pe: “Pe Oluwa re fun wa, ki O fi ye wa, ewo ni.” O so pe: "Dajudaju O n so pe abo maalu ni. Ko nii je ogbologboo, ko si nii je godogbo. O maa wa laaarin (mejeeji) yen. Nitori naa, e se ohun ti Won n pa yin lase
قَالُوا ادْعُ لَنَا رَبَّكَ يُبَيِّنْ لَنَا مَا لَوْنُهَا ۚ قَالَ إِنَّهُ يَقُولُ إِنَّهَا بَقَرَةٌ صَفْرَاءُ فَاقِعٌ لَوْنُهَا تَسُرُّ النَّاظِرِينَ
Won wi pe: “Pe Oluwa re fun wa, ki O fi ye wa, ki ni awo re.” O so pe: “Dajudaju O n so pe abo maalu, alawo omi-osan ni. Awo re yo si mo fonifoni, ti o maa dun-un wo l’oju awon oluworan
قَالُوا ادْعُ لَنَا رَبَّكَ يُبَيِّنْ لَنَا مَا هِيَ إِنَّ الْبَقَرَ تَشَابَهَ عَلَيْنَا وَإِنَّا إِنْ شَاءَ اللَّهُ لَمُهْتَدُونَ
Won wi pe: "Pe Oluwa re fun wa, ki O fi ye wa, ewo ni. Dajudaju awon abo maalu jora won loju wa. Ati pe dajudaju, ti Allahu ba fe, awa maa mona (ti a o gba ri i)
قَالَ إِنَّهُ يَقُولُ إِنَّهَا بَقَرَةٌ لَا ذَلُولٌ تُثِيرُ الْأَرْضَ وَلَا تَسْقِي الْحَرْثَ مُسَلَّمَةٌ لَا شِيَةَ فِيهَا ۚ قَالُوا الْآنَ جِئْتَ بِالْحَقِّ ۚ فَذَبَحُوهَا وَمَا كَادُوا يَفْعَلُونَ
O so pe: “Dajudaju O n so pe abo maalu ni. Ko nii je maalu yepere ti n roko. Ko si nii maa fomi won oko. O maa ni alaafia, ko si nii ni abawon kan lara.” Won wi pe: “Nisinsin yii l’o mu ododo wa.” Won si pa maalu naa. Won fee ma se e mo
وَإِذْ قَتَلْتُمْ نَفْسًا فَادَّارَأْتُمْ فِيهَا ۖ وَاللَّهُ مُخْرِجٌ مَا كُنْتُمْ تَكْتُمُونَ
(E ranti) nigba ti e pa eni kan, e si n ti i sira yin. Allahu yo si safi han ohun ti e n fi pamo

Choose other languages: