Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Baqara Ayahs #280 Translated in Yoruba

يَمْحَقُ اللَّهُ الرِّبَا وَيُرْبِي الصَّدَقَاتِ ۗ وَاللَّهُ لَا يُحِبُّ كُلَّ كَفَّارٍ أَثِيمٍ
Allahu maa run owo ele. O si maa bu si awon ore. Allahu ko nifee gbogbo alaigbagbo, elese
إِنَّ الَّذِينَ آمَنُوا وَعَمِلُوا الصَّالِحَاتِ وَأَقَامُوا الصَّلَاةَ وَآتَوُا الزَّكَاةَ لَهُمْ أَجْرُهُمْ عِنْدَ رَبِّهِمْ وَلَا خَوْفٌ عَلَيْهِمْ وَلَا هُمْ يَحْزَنُونَ
Dajudaju awon t’o gbagbo ni ododo, ti won se awon ise rere, ti won kirun, ti won si yo Zakah, esan won n be fun won ni odo Oluwa won. Ko si ipaya fun won. Won ko si nii banuje
يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا اتَّقُوا اللَّهَ وَذَرُوا مَا بَقِيَ مِنَ الرِّبَا إِنْ كُنْتُمْ مُؤْمِنِينَ
Eyin ti e gbagbo ni ododo, e beru Allahu, ki e si fi ohun t’o seku ninu ele sile, ti e ba je onigbagbo ododo
فَإِنْ لَمْ تَفْعَلُوا فَأْذَنُوا بِحَرْبٍ مِنَ اللَّهِ وَرَسُولِهِ ۖ وَإِنْ تُبْتُمْ فَلَكُمْ رُءُوسُ أَمْوَالِكُمْ لَا تَظْلِمُونَ وَلَا تُظْلَمُونَ
Ti e o ba se bee, e lo mo pe ogun kan lati odo Allahu ati Ojise Re (n bo wa ba yin). Ti e ba si ronu piwada, tiyin ni oju-owo yin. E o nii sabosi (si won). Won ko si nii sabosi si yin
وَإِنْ كَانَ ذُو عُسْرَةٍ فَنَظِرَةٌ إِلَىٰ مَيْسَرَةٍ ۚ وَأَنْ تَصَدَّقُوا خَيْرٌ لَكُمْ ۖ إِنْ كُنْتُمْ تَعْلَمُونَ
Ti (onigbese) ba je eni ti ara n ni, e wo o niran di asiko idera. Ati pe ki e fi se saraa (fun un) loore julo fun yin, ti e ba mo

Choose other languages: