Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Balad Ayahs #17 Translated in Yoruba

فَكُّ رَقَبَةٍ
(Ohun ni) titu eru sile loko eru
أَوْ إِطْعَامٌ فِي يَوْمٍ ذِي مَسْغَبَةٍ
Tabi fifun eniyan ni ounje ni ojo ebi
يَتِيمًا ذَا مَقْرَبَةٍ
(O le je) omo-orukan ninu ebi
أَوْ مِسْكِينًا ذَا مَتْرَبَةٍ
tabi mekunnu, eni ileele
ثُمَّ كَانَ مِنَ الَّذِينَ آمَنُوا وَتَوَاصَوْا بِالصَّبْرِ وَتَوَاصَوْا بِالْمَرْحَمَةِ
Leyin naa, ki o wa ninu awon t’o gbagbo ni ododo, ti won n gbara won niyanju suuru sise, ti won si tun n gbara won niyanju aanu sise

Choose other languages: