Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Balad Ayahs #19 Translated in Yoruba

يَتِيمًا ذَا مَقْرَبَةٍ
(O le je) omo-orukan ninu ebi
أَوْ مِسْكِينًا ذَا مَتْرَبَةٍ
tabi mekunnu, eni ileele
ثُمَّ كَانَ مِنَ الَّذِينَ آمَنُوا وَتَوَاصَوْا بِالصَّبْرِ وَتَوَاصَوْا بِالْمَرْحَمَةِ
Leyin naa, ki o wa ninu awon t’o gbagbo ni ododo, ti won n gbara won niyanju suuru sise, ti won si tun n gbara won niyanju aanu sise
أُولَٰئِكَ أَصْحَابُ الْمَيْمَنَةِ
Awon wonyen ni ero owo otun
وَالَّذِينَ كَفَرُوا بِآيَاتِنَا هُمْ أَصْحَابُ الْمَشْأَمَةِ
Awon t’o si sai gbagbo ninu awon ayah Wa, awon ni ero owo osi

Choose other languages: