Quran Apps in many lanuages:

Surah Adh-Dhariyat Ayahs #52 Translated in Yoruba

وَالْأَرْضَ فَرَشْنَاهَا فَنِعْمَ الْمَاهِدُونَ
Ati ile, A se e ni ite. Awon olutele-sile si dara
وَمِنْ كُلِّ شَيْءٍ خَلَقْنَا زَوْجَيْنِ لَعَلَّكُمْ تَذَكَّرُونَ
Ati pe gbogbo nnkan ni A seda ni orisi meji-meji nitori ki e le lo iranti
فَفِرُّوا إِلَى اللَّهِ ۖ إِنِّي لَكُمْ مِنْهُ نَذِيرٌ مُبِينٌ
Nitori naa, e sa lo si odo Allahu (nipa ironupiwada). Dajudaju emi ni olukilo ponnbele fun yin lati odo Re
وَلَا تَجْعَلُوا مَعَ اللَّهِ إِلَٰهًا آخَرَ ۖ إِنِّي لَكُمْ مِنْهُ نَذِيرٌ مُبِينٌ
E ma se mu olohun miiran mo Allahu. Dajudaju emi ni olukilo ponnbele fun yin lati odo Re
كَذَٰلِكَ مَا أَتَى الَّذِينَ مِنْ قَبْلِهِمْ مِنْ رَسُولٍ إِلَّا قَالُوا سَاحِرٌ أَوْ مَجْنُونٌ
Bayen ni (oro se ri)! Ojise kan ko wa ba awon t’o siwaju won afi ki won wi pe: "Opidan tabi were ni

Choose other languages: