Quran Apps in many lanuages:

Surah Adh-Dhariyat Ayahs #54 Translated in Yoruba

فَفِرُّوا إِلَى اللَّهِ ۖ إِنِّي لَكُمْ مِنْهُ نَذِيرٌ مُبِينٌ
Nitori naa, e sa lo si odo Allahu (nipa ironupiwada). Dajudaju emi ni olukilo ponnbele fun yin lati odo Re
وَلَا تَجْعَلُوا مَعَ اللَّهِ إِلَٰهًا آخَرَ ۖ إِنِّي لَكُمْ مِنْهُ نَذِيرٌ مُبِينٌ
E ma se mu olohun miiran mo Allahu. Dajudaju emi ni olukilo ponnbele fun yin lati odo Re
كَذَٰلِكَ مَا أَتَى الَّذِينَ مِنْ قَبْلِهِمْ مِنْ رَسُولٍ إِلَّا قَالُوا سَاحِرٌ أَوْ مَجْنُونٌ
Bayen ni (oro se ri)! Ojise kan ko wa ba awon t’o siwaju won afi ki won wi pe: "Opidan tabi were ni
أَتَوَاصَوْا بِهِ ۚ بَلْ هُمْ قَوْمٌ طَاغُونَ
Se won so asoole nipa re laaarin ara won ni? Rara o! Ijo olutayo-enu-ala ni won ni
فَتَوَلَّ عَنْهُمْ فَمَا أَنْتَ بِمَلُومٍ
Nitori naa, seri kuro lodo won na. Iwo ki i se alabuku

Choose other languages: