Quran Apps in many lanuages:

Surah Adh-Dhariyat Ayahs #56 Translated in Yoruba

كَذَٰلِكَ مَا أَتَى الَّذِينَ مِنْ قَبْلِهِمْ مِنْ رَسُولٍ إِلَّا قَالُوا سَاحِرٌ أَوْ مَجْنُونٌ
Bayen ni (oro se ri)! Ojise kan ko wa ba awon t’o siwaju won afi ki won wi pe: "Opidan tabi were ni
أَتَوَاصَوْا بِهِ ۚ بَلْ هُمْ قَوْمٌ طَاغُونَ
Se won so asoole nipa re laaarin ara won ni? Rara o! Ijo olutayo-enu-ala ni won ni
فَتَوَلَّ عَنْهُمْ فَمَا أَنْتَ بِمَلُومٍ
Nitori naa, seri kuro lodo won na. Iwo ki i se alabuku
وَذَكِّرْ فَإِنَّ الذِّكْرَىٰ تَنْفَعُ الْمُؤْمِنِينَ
Seranti nitori pe, dajudaju iranti maa wulo fun awon onigbagbo ododo
وَمَا خَلَقْتُ الْجِنَّ وَالْإِنْسَ إِلَّا لِيَعْبُدُونِ
Ati pe Emi ko seda alujannu ati eniyan bi ko se pe ki won le josin fun Mi

Choose other languages: