Quran Apps in many lanuages:

Surah Adh-Dhariyat Ayahs #27 Translated in Yoruba

فَوَرَبِّ السَّمَاءِ وَالْأَرْضِ إِنَّهُ لَحَقٌّ مِثْلَ مَا أَنَّكُمْ تَنْطِقُونَ
Nitori naa, Mo fi Oluwa sanmo ati ile bura, dajudaju ododo ni (oro naa) gege bi o se je ododo pe e n fenu soro
هَلْ أَتَاكَ حَدِيثُ ضَيْفِ إِبْرَاهِيمَ الْمُكْرَمِينَ
Nje oro awon alejo (Anabi) ’Ibrohim, awon alapon-onle, ti de odo re
إِذْ دَخَلُوا عَلَيْهِ فَقَالُوا سَلَامًا ۖ قَالَ سَلَامٌ قَوْمٌ مُنْكَرُونَ
(Ranti) nigba ti won wole to o wa, won si so pe: "Alaafia (fun o)." Oun naa so pe: "Alaafia (fun yin), eyin ajoji eniyan
فَرَاغَ إِلَىٰ أَهْلِهِ فَجَاءَ بِعِجْلٍ سَمِينٍ
O lo si odo awon ara ile re, o si de pelu omo maalu oloraa (ayangbe)
فَقَرَّبَهُ إِلَيْهِمْ قَالَ أَلَا تَأْكُلُونَ
O gbe e sunmo odo won. O si so pe: "Se e o nii jeun ni

Choose other languages: