Quran Apps in many lanuages:

Surah Abasa Ayahs #26 Translated in Yoruba

ثُمَّ إِذَا شَاءَ أَنْشَرَهُ
Leyin naa, nigba ti Allahu ba fe, O maa gbe e dide
كَلَّا لَمَّا يَقْضِ مَا أَمَرَهُ
E gbo, eniyan ko ti i se nnkan ti Allahu pa lase fun un
فَلْيَنْظُرِ الْإِنْسَانُ إِلَىٰ طَعَامِهِ
Nitori naa, ki eniyan woye si ounje re
أَنَّا صَبَبْنَا الْمَاءَ صَبًّا
Dajudaju Awa n ro ojo ni pupo
ثُمَّ شَقَقْنَا الْأَرْضَ شَقًّا
Leyin naa, A mu ile san kankan

Choose other languages: