Quran Apps in many lanuages:

Surah Aal-E-Imran Ayahs #102 Translated in Yoruba

قُلْ يَا أَهْلَ الْكِتَابِ لِمَ تَكْفُرُونَ بِآيَاتِ اللَّهِ وَاللَّهُ شَهِيدٌ عَلَىٰ مَا تَعْمَلُونَ
So pe: "Eyin ahlul-kitab, nitori ki ni e oo fi sai gbagbo ninu awon ayah Allahu? Allahu si ni Arinu-rode ohun ti e n se nise
قُلْ يَا أَهْلَ الْكِتَابِ لِمَ تَصُدُّونَ عَنْ سَبِيلِ اللَّهِ مَنْ آمَنَ تَبْغُونَهَا عِوَجًا وَأَنْتُمْ شُهَدَاءُ ۗ وَمَا اللَّهُ بِغَافِلٍ عَمَّا تَعْمَلُونَ
So pe: "Eyin ahlul-kitab, nitori ki ni e fi n seri eni t’o gbagbo lododo kuro loju ona (esin) Allahu, e si n fe ko wo, e si jerii (si ododo ’Islam)? Allahu ki i se Onigbagbe nipa ohun ti e n se nise
يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا إِنْ تُطِيعُوا فَرِيقًا مِنَ الَّذِينَ أُوتُوا الْكِتَابَ يَرُدُّوكُمْ بَعْدَ إِيمَانِكُمْ كَافِرِينَ
Eyin ti e gbagbo ni ododo, ti e ba tele apa kan ninu awon ti A fun ni tira, won maa da yin pada leyin igbagbo ododo yin si ipo alaigbagbo
وَكَيْفَ تَكْفُرُونَ وَأَنْتُمْ تُتْلَىٰ عَلَيْكُمْ آيَاتُ اللَّهِ وَفِيكُمْ رَسُولُهُ ۗ وَمَنْ يَعْتَصِمْ بِاللَّهِ فَقَدْ هُدِيَ إِلَىٰ صِرَاطٍ مُسْتَقِيمٍ
Bawo ni eyin se le sai gbagbo, eyin ma ni won n ke awon ayah Allahu fun, Ojise Re si wa laaarin yin! Enikeni ti o ba duro sinsin ti Allahu, A ti to o si ona taara
يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا اتَّقُوا اللَّهَ حَقَّ تُقَاتِهِ وَلَا تَمُوتُنَّ إِلَّا وَأَنْتُمْ مُسْلِمُونَ
Eyin ti e gbagbo ni ododo, e beru Allahu bi o se to lati beru Re. Eyin ko si gbodo ku ayafi ki e wa ni ipo musulumi

Choose other languages: