Quran Apps in many lanuages:

Surah Aal-E-Imran Ayahs #90 Translated in Yoruba

كَيْفَ يَهْدِي اللَّهُ قَوْمًا كَفَرُوا بَعْدَ إِيمَانِهِمْ وَشَهِدُوا أَنَّ الرَّسُولَ حَقٌّ وَجَاءَهُمُ الْبَيِّنَاتُ ۚ وَاللَّهُ لَا يَهْدِي الْقَوْمَ الظَّالِمِينَ
Bawo ni Allahu yo se fi ona mo ijo kan t’o sai gbagbo leyin igbagbo won? Won si jerii pe dajudaju Ojise naa, ododo ni. Awon eri t’o yanju si ti de ba won. Allahu ki i fi ona mo ijo alabosi
أُولَٰئِكَ جَزَاؤُهُمْ أَنَّ عَلَيْهِمْ لَعْنَةَ اللَّهِ وَالْمَلَائِكَةِ وَالنَّاسِ أَجْمَعِينَ
Awon wonyen, esan won ni pe, dajudaju egun Allahu ati (egun) awon molaika ati (egun) gbogbo awon eniyan n be lori won
خَالِدِينَ فِيهَا لَا يُخَفَّفُ عَنْهُمُ الْعَذَابُ وَلَا هُمْ يُنْظَرُونَ
Olusegbere ni won ninu egun. Nitori naa, A o nii gbe iya fuye fun won, A o si nii fun won ni isinmi (ninu Ina)
إِلَّا الَّذِينَ تَابُوا مِنْ بَعْدِ ذَٰلِكَ وَأَصْلَحُوا فَإِنَّ اللَّهَ غَفُورٌ رَحِيمٌ
Ayafi awon t’o ronu piwada leyin iyen, ti won si se atunse, nitori pe dajudaju Allahu ni Alaforijin, Asake-orun
إِنَّ الَّذِينَ كَفَرُوا بَعْدَ إِيمَانِهِمْ ثُمَّ ازْدَادُوا كُفْرًا لَنْ تُقْبَلَ تَوْبَتُهُمْ وَأُولَٰئِكَ هُمُ الضَّالُّونَ
Dajudaju awon t’o sai gbagbo leyin igbagbo won, leyin naa, won lekun ni aigbagbo, A o nii gba ironupiwada won. Awon wonyen ni olusina

Choose other languages: