Quran Apps in many lanuages:

Surah Aal-E-Imran Ayahs #56 Translated in Yoruba

فَلَمَّا أَحَسَّ عِيسَىٰ مِنْهُمُ الْكُفْرَ قَالَ مَنْ أَنْصَارِي إِلَى اللَّهِ ۖ قَالَ الْحَوَارِيُّونَ نَحْنُ أَنْصَارُ اللَّهِ آمَنَّا بِاللَّهِ وَاشْهَدْ بِأَنَّا مُسْلِمُونَ
Nigba ti (Anabi) ‘Isa fura si aigbagbo lodo won (pe won fe pa oun), o so pe: “Ta ni oluranlowo mi si odo Allahu?” Awon omoleyin (re) so pe: "Awa ni oluranlowo fun (esin) Allahu. A gba Allahu gbo. Ki o si jerii pe dajudaju musulumi ni wa
رَبَّنَا آمَنَّا بِمَا أَنْزَلْتَ وَاتَّبَعْنَا الرَّسُولَ فَاكْتُبْنَا مَعَ الشَّاهِدِينَ
Oluwa wa, a gbagbo ninu ohun ti O sokale. A si tele Ojise. Nitori naa, ko wa mo awon olujerii
وَمَكَرُوا وَمَكَرَ اللَّهُ ۖ وَاللَّهُ خَيْرُ الْمَاكِرِينَ
Won dete, Allahu si dete. Allahu si l’oore julo ninu awon adete
إِذْ قَالَ اللَّهُ يَا عِيسَىٰ إِنِّي مُتَوَفِّيكَ وَرَافِعُكَ إِلَيَّ وَمُطَهِّرُكَ مِنَ الَّذِينَ كَفَرُوا وَجَاعِلُ الَّذِينَ اتَّبَعُوكَ فَوْقَ الَّذِينَ كَفَرُوا إِلَىٰ يَوْمِ الْقِيَامَةِ ۖ ثُمَّ إِلَيَّ مَرْجِعُكُمْ فَأَحْكُمُ بَيْنَكُمْ فِيمَا كُنْتُمْ فِيهِ تَخْتَلِفُونَ
Wafat/wafah si tumo si ""ƙobd"" gbigba eni kan kuro lowo eni kan ninu surah ali ‘Imron 3:55 ati surah al-Mo’dah elesin ’Islam ni awon t’o tele ‘Isa omo Moryam (’alaehi-ssolatu wa-ssalam). Ati ‘Isa omo Moryam (’alaehi-ssolatu wa-ssalam) ati owo awon t’o tele e loju aye re musulumi ni won gege bi won se pera won bee ninu surah yii
فَأَمَّا الَّذِينَ كَفَرُوا فَأُعَذِّبُهُمْ عَذَابًا شَدِيدًا فِي الدُّنْيَا وَالْآخِرَةِ وَمَا لَهُمْ مِنْ نَاصِرِينَ
Ni ti awon t’o sai gbagbo, Emi yoo je won niya lile ni aye ati ni orun. Ko si nii si awon oluranlowo fun won

Choose other languages: