Quran Apps in many lanuages:

Surah Aal-E-Imran Ayahs #20 Translated in Yoruba

الَّذِينَ يَقُولُونَ رَبَّنَا إِنَّنَا آمَنَّا فَاغْفِرْ لَنَا ذُنُوبَنَا وَقِنَا عَذَابَ النَّارِ
awon t’o n so pe: "Oluwa wa, dajudaju awa gbagbo. Nitori naa, fori awon ese wa jin wa. Ki O si so wa nibi iya Ina
الصَّابِرِينَ وَالصَّادِقِينَ وَالْقَانِتِينَ وَالْمُنْفِقِينَ وَالْمُسْتَغْفِرِينَ بِالْأَسْحَارِ
(Ogba Idera yen wa fun) awon onisuuru, awon olododo, awon olutele-ase Allahu, awon olunawo-fesin ati awon olutoro-aforijin ni asiko saari
شَهِدَ اللَّهُ أَنَّهُ لَا إِلَٰهَ إِلَّا هُوَ وَالْمَلَائِكَةُ وَأُولُو الْعِلْمِ قَائِمًا بِالْقِسْطِ ۚ لَا إِلَٰهَ إِلَّا هُوَ الْعَزِيزُ الْحَكِيمُ
Allahu jerii pe dajudaju ko si olohun kan ti ijosin to si afi Oun. Awon molaika ati onimo esin (tun jerii bee.), Allahu ni Onideede. Ko si olohun kan ti ijosin to si afi Oun, Alagbara, Ologbon
إِنَّ الدِّينَ عِنْدَ اللَّهِ الْإِسْلَامُ ۗ وَمَا اخْتَلَفَ الَّذِينَ أُوتُوا الْكِتَابَ إِلَّا مِنْ بَعْدِ مَا جَاءَهُمُ الْعِلْمُ بَغْيًا بَيْنَهُمْ ۗ وَمَنْ يَكْفُرْ بِآيَاتِ اللَّهِ فَإِنَّ اللَّهَ سَرِيعُ الْحِسَابِ
Dajudaju esin t’o wa lodo Allahu ni ’Islam. Awon ti A fun ni Tira (awon yehudi ati kristieni) ko yapa enu (si esin naa) afi leyin ti imo de ba won. (Won se bee) nipase ote aarin won (si awon Anabi). Eni t’o ba sai gbagbo ninu awon ayah Allahu, dajudaju Allahu ni Oluyara nibi isiro-ise
فَإِنْ حَاجُّوكَ فَقُلْ أَسْلَمْتُ وَجْهِيَ لِلَّهِ وَمَنِ اتَّبَعَنِ ۗ وَقُلْ لِلَّذِينَ أُوتُوا الْكِتَابَ وَالْأُمِّيِّينَ أَأَسْلَمْتُمْ ۚ فَإِنْ أَسْلَمُوا فَقَدِ اهْتَدَوْا ۖ وَإِنْ تَوَلَّوْا فَإِنَّمَا عَلَيْكَ الْبَلَاغُ ۗ وَاللَّهُ بَصِيرٌ بِالْعِبَادِ
Ti won ba si ja o niyan, so pe: “Emi ati eni ti o tele mi juwo juse sile fun Allahu.” Ki o si so fun awon ti A fun ni Tira ati awon alaimoonkomoonka (alainitira) pe: “Se e maa gba ’Islam?” Ti won ba gba ’Islam, won ti mona. Ti won ba si keyin (si ’Islam), ise-jije nikan ni ojuse tire. Allahu si ni Oluriran nipa awon erusin

Choose other languages: