Quran Apps in many lanuages:

Surah At-Tin Ayahs #6 Translated in Yoruba

وَطُورِ سِينِينَ
O tun bura pelu apata Sinin
وَهَٰذَا الْبَلَدِ الْأَمِينِ
O tun bura pelu ilu ifayabale yii
لَقَدْ خَلَقْنَا الْإِنْسَانَ فِي أَحْسَنِ تَقْوِيمٍ
Dajudaju A seda eniyan pelu irisi t’o dara julo
ثُمَّ رَدَدْنَاهُ أَسْفَلَ سَافِلِينَ
Leyin naa, A maa da a pada si isale patapata (ninu Ina)
إِلَّا الَّذِينَ آمَنُوا وَعَمِلُوا الصَّالِحَاتِ فَلَهُمْ أَجْرٌ غَيْرُ مَمْنُونٍ
Ayafi awon t’o gbagbo ni ododo, ti won si se awon ise rere. Nitori naa, esan ti ko nii pin (ti ko nii pedin) n be fun won

Choose other languages: