Quran Apps in many lanuages:

Surah Ash-Shams Ayahs #4 Translated in Yoruba

وَالشَّمْسِ وَضُحَاهَا
(Allahu) bura pelu oorun ati iyaleta re
وَالْقَمَرِ إِذَا تَلَاهَا
O tun bura pelu osupa nigba ti o ba (yo) tele (oorun)
وَالنَّهَارِ إِذَا جَلَّاهَا
O tun bura pelu osan nigba ti o ba mu imole ba okunkun oru
وَاللَّيْلِ إِذَا يَغْشَاهَا
O tun bura pelu ale nigba ti o ba bo osan mole

Choose other languages: