Quran Apps in many lanuages:

Surah Ar-Rahman Ayahs #30 Translated in Yoruba

كُلُّ مَنْ عَلَيْهَا فَانٍ
Gbogbo eni t’o wa lori ile maa tan
وَيَبْقَىٰ وَجْهُ رَبِّكَ ذُو الْجَلَالِ وَالْإِكْرَامِ
Oju Oluwa re, Atobi, Alapon-onle si maa wa titi laelae
فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
يَسْأَلُهُ مَنْ فِي السَّمَاوَاتِ وَالْأَرْضِ ۚ كُلَّ يَوْمٍ هُوَ فِي شَأْنٍ
Awon t’o wa ninu awon sanmo ati ile n beere (nnkan) lodo Re; O si wa lori ise lojoojumo
فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro

Choose other languages: