Quran Apps in many lanuages:

Surah Ar-Rahman Ayahs #27 Translated in Yoruba

فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
وَلَهُ الْجَوَارِ الْمُنْشَآتُ فِي الْبَحْرِ كَالْأَعْلَامِ
Ti (Allahu) ni awon oko oju-omi gogoro t’o n rin ninu agbami odo (ti won da) bi apata giga
فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
كُلُّ مَنْ عَلَيْهَا فَانٍ
Gbogbo eni t’o wa lori ile maa tan
وَيَبْقَىٰ وَجْهُ رَبِّكَ ذُو الْجَلَالِ وَالْإِكْرَامِ
Oju Oluwa re, Atobi, Alapon-onle si maa wa titi laelae

Choose other languages: