Quran Apps in many lanuages:

Surah Ar-Rahman Ayahs #22 Translated in Yoruba

فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
مَرَجَ الْبَحْرَيْنِ يَلْتَقِيَانِ
(Allahu) mu odo meji (odo oniyo ati odo aladun) san pade ara won
بَيْنَهُمَا بَرْزَخٌ لَا يَبْغِيَانِ
Gaga kan si wa laaarin awon mejeeji ti won ko si le tayo enu-ala (re laaarin ara won)
فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
يَخْرُجُ مِنْهُمَا اللُّؤْلُؤُ وَالْمَرْجَانُ
Okuta oniyebiye ati ileke iyun n jade ninu awon (odo) mejeeji naa

Choose other languages: