Quran Apps in many lanuages:

Surah An-Nisa Ayahs #108 Translated in Yoruba

وَلَا تَهِنُوا فِي ابْتِغَاءِ الْقَوْمِ ۖ إِنْ تَكُونُوا تَأْلَمُونَ فَإِنَّهُمْ يَأْلَمُونَ كَمَا تَأْلَمُونَ ۖ وَتَرْجُونَ مِنَ اللَّهِ مَا لَا يَرْجُونَ ۗ وَكَانَ اللَّهُ عَلِيمًا حَكِيمًا
E ma se kaaare nipa wiwa awon eniyan naa (lati ja won logun). Ti eyin ba n je irora (ogbe), dajudaju awon naa n je irora (ogbe) gege bi eyin naa se n je irora. Eyin si n reti ohun ti awon ko reti lodo Allahu. Allahu si n je Onimo, Ologbon
إِنَّا أَنْزَلْنَا إِلَيْكَ الْكِتَابَ بِالْحَقِّ لِتَحْكُمَ بَيْنَ النَّاسِ بِمَا أَرَاكَ اللَّهُ ۚ وَلَا تَكُنْ لِلْخَائِنِينَ خَصِيمًا
Dajudaju Awa so Tira (al-Ƙur’an) kale fun o pelu ododo nitori ki o le baa sedajo laaarin awon eniyan pelu ohun ti Allahu fi han o. Ma se je olugbeja fun awon onijanba
وَاسْتَغْفِرِ اللَّهَ ۖ إِنَّ اللَّهَ كَانَ غَفُورًا رَحِيمًا
Toro aforijin lodo Allahu, dajudaju Allahu, O n je Alaforijin, Asake-orun
وَلَا تُجَادِلْ عَنِ الَّذِينَ يَخْتَانُونَ أَنْفُسَهُمْ ۚ إِنَّ اللَّهَ لَا يُحِبُّ مَنْ كَانَ خَوَّانًا أَثِيمًا
Ma se ba awon t’o n janba emi ara won wa awijare. Dajudaju Allahu ko feran enikeni ti o je onijanba, elese
يَسْتَخْفُونَ مِنَ النَّاسِ وَلَا يَسْتَخْفُونَ مِنَ اللَّهِ وَهُوَ مَعَهُمْ إِذْ يُبَيِّتُونَ مَا لَا يَرْضَىٰ مِنَ الْقَوْلِ ۚ وَكَانَ اللَّهُ بِمَا يَعْمَلُونَ مُحِيطًا
Won n fi ara pamo fun awon eniyan, won ko si le fara pamo fun Allahu (nitori pe) O wa pelu won (pelu imo Re) nigba ti won n gbimo ohun ti (Allahu) ko yonu si ninu oro siso. Allahu si n je Alamotan nipa ohun ti won n se nise

Choose other languages: