Quran Apps in many lanuages:

Surah An-Nas Ayahs #6 Translated in Yoruba

مَلِكِ النَّاسِ
Oba awon eniyan
إِلَٰهِ النَّاسِ
Olohun awon eniyan
مِنْ شَرِّ الْوَسْوَاسِ الْخَنَّاسِ
nibi aburu (Esu) oniroyiroyi, olusaseyin (fun eni t’o ba daruko Allah)
الَّذِي يُوَسْوِسُ فِي صُدُورِ النَّاسِ
(Esu ni) eni ti o n ko royiroyi sinu awon okan eniyan
مِنَ الْجِنَّةِ وَالنَّاسِ
(Esu naa) wa ninu alujannu ati eniyan

Choose other languages: