Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Sharh Ayahs #8 Translated in Yoruba

فَإِنَّ مَعَ الْعُسْرِ يُسْرًا
Nitori naa, dajudaju idekun wa leyin inira
إِنَّ مَعَ الْعُسْرِ يُسْرًا
Dajudaju idekun wa leyin inira se
فَإِذَا فَرَغْتَ فَانْصَبْ
Nitori naa, nigba ti o ba buse (lori okan), gbiyanju (omiran)
وَإِلَىٰ رَبِّكَ فَارْغَبْ
Odo Oluwa re si ni ki o soju kokoro oore si

Choose other languages: