Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Maun Ayahs #7 Translated in Yoruba

فَوَيْلٌ لِلْمُصَلِّينَ
Egbe ni fun awon (munaafiki) t’o n kirun; ko tumo si “ohun t’o n run eniyan”. Amo itumo “irun” ni “ohun t’o n run ese olukirun” nitori pe ti olukirun ba ti se aluwala ni o ti san gbogbo awon ese weere ti o ti fi awon orikee ara re se siwaju. Bakan naa
الَّذِينَ هُمْ عَنْ صَلَاتِهِمْ سَاهُونَ
awon t’o n gbagbe lati kirun won ni asiko re
الَّذِينَ هُمْ يُرَاءُونَ
awon t’o n se sekarimi
وَيَمْنَعُونَ الْمَاعُونَ
ati pe won n hanna ohun elo (fun awon eniyan)

Choose other languages: