Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Lail Ayahs #6 Translated in Yoruba

وَالنَّهَارِ إِذَا تَجَلَّىٰ
O tun bura pelu osan nigba ti (osan) ba pon
وَمَا خَلَقَ الذَّكَرَ وَالْأُنْثَىٰ
O tun bura pelu Eni ti O da ako ati abo
إِنَّ سَعْيَكُمْ لَشَتَّىٰ
Dajudaju ise yin, otooto ni
فَأَمَّا مَنْ أَعْطَىٰ وَاتَّقَىٰ
Ni ti eni ti o ba tore, ti o si beru (Allahu)
وَصَدَّقَ بِالْحُسْنَىٰ
(ti) o tun pe esan rere ni ododo

Choose other languages: