Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Lail Ayahs #18 Translated in Yoruba

فَأَنْذَرْتُكُمْ نَارًا تَلَظَّىٰ
Nitori naa, Mo ti fi Ina elejo fofo kilo fun yin
لَا يَصْلَاهَا إِلَّا الْأَشْقَى
Ko si eni ti o maa wo inu re afi olori buruku
الَّذِي كَذَّبَ وَتَوَلَّىٰ
eni ti o pe ododo niro, ti o si keyin si i
وَسَيُجَنَّبُهَا الْأَتْقَى
Won si maa gbe (Ina) jinna si oluberu (Allahu)
الَّذِي يُؤْتِي مَالَهُ يَتَزَكَّىٰ
eni t’o n fi dukia re tore, ti o n safomo (re)

Choose other languages: