Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Haaqqa Ayahs #31 Translated in Yoruba

يَا لَيْتَهَا كَانَتِ الْقَاضِيَةَ
Haa! Ki iku si je opin (oro eda)
مَا أَغْنَىٰ عَنِّي مَالِيَهْ ۜ
Dukia mi ko si ro mi loro
هَلَكَ عَنِّي سُلْطَانِيَهْ
Agbara mi si ti parun
خُذُوهُ فَغُلُّوهُ
E mu un, ki e de e ni owo mo orun
ثُمَّ الْجَحِيمَ صَلُّوهُ
Leyin naa, inu ina Jehim ni ki e mu un wo

Choose other languages: