Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Anaam Ayahs #107 Translated in Yoruba

لَا تُدْرِكُهُ الْأَبْصَارُ وَهُوَ يُدْرِكُ الْأَبْصَارَ ۖ وَهُوَ اللَّطِيفُ الْخَبِيرُ
Awon oju (eda) ko le ka Allahu. Oun si ka awon oju. Oun si ni Alaaanu, Alamotan
قَدْ جَاءَكُمْ بَصَائِرُ مِنْ رَبِّكُمْ ۖ فَمَنْ أَبْصَرَ فَلِنَفْسِهِ ۖ وَمَنْ عَمِيَ فَعَلَيْهَا ۚ وَمَا أَنَا عَلَيْكُمْ بِحَفِيظٍ
Awon eri t’o daju kuku ti de ba yin lati odo Oluwa yin. Nitori naa, enikeni t’o ba riran, fun emi ara re ni. Enikeni t’o ba si foju, fun emi ara re ni. Emi ki i se oluso lori yin
وَكَذَٰلِكَ نُصَرِّفُ الْآيَاتِ وَلِيَقُولُوا دَرَسْتَ وَلِنُبَيِّنَهُ لِقَوْمٍ يَعْلَمُونَ
Bayen ni A se n mu awon ayah wa loniran-anran ona nitori ki won le wi pe: "O kekoo (re lodo awon eniyan ni." Dipo ki won wi pe: "Won so o kale fun o ni." ati nitori ki A le se alaye re fun awon eniyan t’o nimo)
اتَّبِعْ مَا أُوحِيَ إِلَيْكَ مِنْ رَبِّكَ ۖ لَا إِلَٰهَ إِلَّا هُوَ ۖ وَأَعْرِضْ عَنِ الْمُشْرِكِينَ
Tele ohun ti won fi ran o ni imisi lati odo Oluwa re. Ko si eni ti ijosin to si afi Oun. Ki o si seri kuro ni odo awon osebo
وَلَوْ شَاءَ اللَّهُ مَا أَشْرَكُوا ۗ وَمَا جَعَلْنَاكَ عَلَيْهِمْ حَفِيظًا ۖ وَمَا أَنْتَ عَلَيْهِمْ بِوَكِيلٍ
Ti o ba je pe Allahu ba fe (imona fun won), won iba ti sebo. A o si fi o se oluso lori won. Ati pe iwo ko ni alamojuuto won

Choose other languages: