Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Ala Ayahs #14 Translated in Yoruba

سَيَذَّكَّرُ مَنْ يَخْشَىٰ
Eni ti o maa paya (Allahu) maa lo iranti
وَيَتَجَنَّبُهَا الْأَشْقَى
Olori-buruku si maa takete si i
الَّذِي يَصْلَى النَّارَ الْكُبْرَىٰ
(Oun si ni) eni ti o maa wo inu Ina t’o tobi
ثُمَّ لَا يَمُوتُ فِيهَا وَلَا يَحْيَىٰ
Leyin naa, ko nii ku sinu re, ko si nii semi (alaafia)
قَدْ أَفْلَحَ مَنْ تَزَكَّىٰ
Dajudaju eni ti o ba safomo (okan re) ti jere

Choose other languages: