Quran Apps in many lanuages:

Surah Adh-Dhariyat Ayahs #24 Translated in Yoruba

وَفِي الْأَرْضِ آيَاتٌ لِلْمُوقِنِينَ
Awon ami wa ni ori ile fun awon alamodaju
وَفِي أَنْفُسِكُمْ ۚ أَفَلَا تُبْصِرُونَ
Ninu emi ara yin gan-an (ami iyanu wa ninu re). Se e o riran ni
وَفِي السَّمَاءِ رِزْقُكُمْ وَمَا تُوعَدُونَ
Arisiki yin ati ohun ti A n se ni adehun fun yin wa ninu sanmo
فَوَرَبِّ السَّمَاءِ وَالْأَرْضِ إِنَّهُ لَحَقٌّ مِثْلَ مَا أَنَّكُمْ تَنْطِقُونَ
Nitori naa, Mo fi Oluwa sanmo ati ile bura, dajudaju ododo ni (oro naa) gege bi o se je ododo pe e n fenu soro
هَلْ أَتَاكَ حَدِيثُ ضَيْفِ إِبْرَاهِيمَ الْمُكْرَمِينَ
Nje oro awon alejo (Anabi) ’Ibrohim, awon alapon-onle, ti de odo re

Choose other languages: