Quran Apps in many lanuages:

Surah Adh-Dhariyat Ayahs #20 Translated in Yoruba

آخِذِينَ مَا آتَاهُمْ رَبُّهُمْ ۚ إِنَّهُمْ كَانُوا قَبْلَ ذَٰلِكَ مُحْسِنِينَ
Won yoo maa gba nnkan ti Oluwa won ba fun won. Dajudaju won ti je oluse-rere siwaju iyen
كَانُوا قَلِيلًا مِنَ اللَّيْلِ مَا يَهْجَعُونَ
Won maa n sun oorun die ninu oru
وَبِالْأَسْحَارِ هُمْ يَسْتَغْفِرُونَ
Won maa n toro aforijin ni afemojumo
وَفِي أَمْوَالِهِمْ حَقٌّ لِلسَّائِلِ وَالْمَحْرُومِ
Ninu dukia won, won ni ojuse ti won n se fun alagbe ati eni ti A se arisiki ni eewo fun
وَفِي الْأَرْضِ آيَاتٌ لِلْمُوقِنِينَ
Awon ami wa ni ori ile fun awon alamodaju

Choose other languages: