Quran Apps in many lanuages:

Surah Aal-E-Imran Ayahs #70 Translated in Yoruba

هَا أَنْتُمْ هَٰؤُلَاءِ حَاجَجْتُمْ فِيمَا لَكُمْ بِهِ عِلْمٌ فَلِمَ تُحَاجُّونَ فِيمَا لَيْسَ لَكُمْ بِهِ عِلْمٌ ۚ وَاللَّهُ يَعْلَمُ وَأَنْتُمْ لَا تَعْلَمُونَ
Eyin ni iwonyi ti e n jiyan nipa ohun ti e nimo nipa re! Ki ni o tun n mu yin jiyan nipa ohun ti e o nimo nipa re? Allahu nimo. Eyin ko si nimo
مَا كَانَ إِبْرَاهِيمُ يَهُودِيًّا وَلَا نَصْرَانِيًّا وَلَٰكِنْ كَانَ حَنِيفًا مُسْلِمًا وَمَا كَانَ مِنَ الْمُشْرِكِينَ
(Anabi) ’Ibrohim ki i se yehudi, ki i se kristieni, sugbon o je oluduro-deede, musulumi. Ko si si ninu awon osebo
إِنَّ أَوْلَى النَّاسِ بِإِبْرَاهِيمَ لَلَّذِينَ اتَّبَعُوهُ وَهَٰذَا النَّبِيُّ وَالَّذِينَ آمَنُوا ۗ وَاللَّهُ وَلِيُّ الْمُؤْمِنِينَ
Dajudaju awon eniyan t’o sunmo (Anabi) ’Ibrohim julo ni awon t’o tele e ati Anabi yii (Anabi Muhammad s.a.w.) ati awon t’o gbagbo ni ododo. Allahu ni Alatileyin fun awon onigbagbo ododo
وَدَّتْ طَائِفَةٌ مِنْ أَهْلِ الْكِتَابِ لَوْ يُضِلُّونَكُمْ وَمَا يُضِلُّونَ إِلَّا أَنْفُسَهُمْ وَمَا يَشْعُرُونَ
Igun kan ninu awon ahlul-kitab fe lati si yin lona. Won ko le si enikeni lona afi ara won, won ko si fura
يَا أَهْلَ الْكِتَابِ لِمَ تَكْفُرُونَ بِآيَاتِ اللَّهِ وَأَنْتُمْ تَشْهَدُونَ
Eyin ahlul-kitab, nitori ki ni e oo fi sai gbagbo ninu awon ayah Allahu, e si n jerii (si ododo re)

Choose other languages: