Quran Apps in many lanuages:

Surah Ibrahim Ayah #52 Translated in Yoruba

هَٰذَا بَلَاغٌ لِلنَّاسِ وَلِيُنْذَرُوا بِهِ وَلِيَعْلَمُوا أَنَّمَا هُوَ إِلَٰهٌ وَاحِدٌ وَلِيَذَّكَّرَ أُولُو الْأَلْبَابِ
Eyi ni ise-jije fun awon eniyan nitori ki won le fi se ikilo, ki won si le mo pe (Allahu) Oun nikan ni Olohun ti ijosin to si, Okan soso, ati nitori ki awon onilaakaye le lo iranti

Choose other languages: