Quran Apps in many lanuages:

Surah Ar-Rahman Ayahs #70 Translated in Yoruba

فِيهِمَا عَيْنَانِ نَضَّاخَتَانِ
Awon odo meji t’o n tu omi jade lai dawo duro wa (ninu ogba mejeeji naa)
فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
فِيهِمَا فَاكِهَةٌ وَنَخْلٌ وَرُمَّانٌ
Eso ipanu, dabinu ati eso rumon wa ninu ogba mejeeji
فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
فِيهِنَّ خَيْرَاتٌ حِسَانٌ
Awon obinrin rere, arewa wa ninu awon Ogba Idera

Choose other languages: