Quran Apps in many lanuages:

Surah Ar-Rahman Ayahs #54 Translated in Yoruba

فِيهِمَا عَيْنَانِ تَجْرِيَانِ
Odo meji t’o n san wa ninu ogba mejeeji
فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
فِيهِمَا مِنْ كُلِّ فَاكِهَةٍ زَوْجَانِ
Orisi meji meji ni eso kookan t’o wa ninu ogba mejeeji
فَبِأَيِّ آلَاءِ رَبِّكُمَا تُكَذِّبَانِ
Nitori naa, ewo ninu awon idera Oluwa eyin eniyan ati alujannu ni e maa pe niro
مُتَّكِئِينَ عَلَىٰ فُرُشٍ بَطَائِنُهَا مِنْ إِسْتَبْرَقٍ ۚ وَجَنَى الْجَنَّتَيْنِ دَانٍ
Won yoo rogboku lori ite, ti awon ite inu re je aran t’o nipon. Awon eso ogba mejeeji si wa ni arowoto

Choose other languages: