Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Sharh Ayahs #5 Translated in Yoruba

أَلَمْ نَشْرَحْ لَكَ صَدْرَكَ
Se A o sipaya igba-aya re fun o bi
وَوَضَعْنَا عَنْكَ وِزْرَكَ
A si gbe ese re kuro lorun re
الَّذِي أَنْقَضَ ظَهْرَكَ
eyi ti o wo o lorun. amo ti onitoun pada gba ’Islam ibaa je pe o gba a ni owuro
وَرَفَعْنَا لَكَ ذِكْرَكَ
A si gbe iranti oruko re ga fun o
فَإِنَّ مَعَ الْعُسْرِ يُسْرًا
Nitori naa, dajudaju idekun wa leyin inira

Choose other languages: