Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Mursalat Ayahs #28 Translated in Yoruba

وَيْلٌ يَوْمَئِذٍ لِلْمُكَذِّبِينَ
Egbe ni ni ojo yen fun awon olupe-ododo-niro
أَلَمْ نَجْعَلِ الْأَرْضَ كِفَاتًا
Nje Awa ko se ile ni ohun t’o n ko eda jo mora won
أَحْيَاءً وَأَمْوَاتًا
(iyen) awon alaaye ati awon oku
وَجَعَلْنَا فِيهَا رَوَاسِيَ شَامِخَاتٍ وَأَسْقَيْنَاكُمْ مَاءً فُرَاتًا
A si fi awon apata gbagidi giga-giga sinu re. A si fun yin ni omi didun mu
وَيْلٌ يَوْمَئِذٍ لِلْمُكَذِّبِينَ
Egbe ni ni ojo yen fun awon olupe-ododo-niro

Choose other languages: