Quran Apps in many lanuages:

Surah Al-Falaq Ayahs #5 Translated in Yoruba

مِنْ شَرِّ مَا خَلَقَ
nibi aburu ohun ti O da
وَمِنْ شَرِّ غَاسِقٍ إِذَا وَقَبَ
ati nibi aburu oru nigba ti o ba sookun
وَمِنْ شَرِّ النَّفَّاثَاتِ فِي الْعُقَدِ
ati nibi aburu awon (opidan) t’o n fenu fategun tuetue sinu awon onde
وَمِنْ شَرِّ حَاسِدٍ إِذَا حَسَدَ
ati nibi aburu onilara nigba ti o ba se ilara

Choose other languages: