Quran Apps in many lanuages:

Surah Adh-Dhariyat Ayahs #47 Translated in Yoruba

وَفِي ثَمُودَ إِذْ قِيلَ لَهُمْ تَمَتَّعُوا حَتَّىٰ حِينٍ
(Ami tun wa) lara ijo Thamud. (Ranti) nigba ti A so fun won pe: "E jaye fun igba die na
فَعَتَوْا عَنْ أَمْرِ رَبِّهِمْ فَأَخَذَتْهُمُ الصَّاعِقَةُ وَهُمْ يَنْظُرُونَ
Won segberaga si ase Oluwa won. Nitori naa, igbe iparun mu won; won si n wo boo
فَمَا اسْتَطَاعُوا مِنْ قِيَامٍ وَمَا كَانُوا مُنْتَصِرِينَ
Won ko le dide naro. Won ko si le ran ara won lowo
وَقَوْمَ نُوحٍ مِنْ قَبْلُ ۖ إِنَّهُمْ كَانُوا قَوْمًا فَاسِقِينَ
Ati ijo Nuh ti o siwaju (won), dajudaju Awa si ni olugbooro
وَالسَّمَاءَ بَنَيْنَاهَا بِأَيْدٍ وَإِنَّا لَمُوسِعُونَ
Ati pe sanmo, A mo on (si oke yin) pelu agbara. Dajudaju Awa si ni olugbooro

Choose other languages: