Quran Apps in many lanuages:

Surah Adh-Dhariyat Ayahs #15 Translated in Yoruba

الَّذِينَ هُمْ فِي غَمْرَةٍ سَاهُونَ
awon ni won wa ninu aimokan, awon onigbagbe
يَسْأَلُونَ أَيَّانَ يَوْمُ الدِّينِ
ti won n beere igba ti Ojo Esan maa sele
يَوْمَ هُمْ عَلَى النَّارِ يُفْتَنُونَ
Ni ojo naa si ni won yoo maa fi Ina je won niya
ذُوقُوا فِتْنَتَكُمْ هَٰذَا الَّذِي كُنْتُمْ بِهِ تَسْتَعْجِلُونَ
E to iya yin wo. Eyi ni nnkan ti e ti n wa pelu ikanju
إِنَّ الْمُتَّقِينَ فِي جَنَّاتٍ وَعُيُونٍ
Dajudaju awon oluberu (Allahu) yoo wa ninu awon Ogba Idera pelu awon omi odo (ni isale re)

Choose other languages: