Quran Apps in many lanuages:

Surah Ad-Dhuha Ayahs #8 Translated in Yoruba

وَلَلْآخِرَةُ خَيْرٌ لَكَ مِنَ الْأُولَىٰ
Dajudaju orun loore fun o ju aye lo
وَلَسَوْفَ يُعْطِيكَ رَبُّكَ فَتَرْضَىٰ
Dajudaju laipe Oluwa re maa fun o ni (oore pupo ni orun). Nitori naa, o si maa yonu si i
أَلَمْ يَجِدْكَ يَتِيمًا فَآوَىٰ
Se (Allahu) ko ri o ni omo-orukan ni? O si fun o ni ibugbe
وَوَجَدَكَ ضَالًّا فَهَدَىٰ
O si ri o ni alaimona (iyen siwaju isokale imisi). O si fi ona mo o
وَوَجَدَكَ عَائِلًا فَأَغْنَىٰ
O tun ri o ni alaini, O si ro o loro

Choose other languages: