Quran Apps in many lanuages:

Surah Aal-E-Imran Ayahs #200 Translated in Yoruba

لَٰكِنِ الَّذِينَ اتَّقَوْا رَبَّهُمْ لَهُمْ جَنَّاتٌ تَجْرِي مِنْ تَحْتِهَا الْأَنْهَارُ خَالِدِينَ فِيهَا نُزُلًا مِنْ عِنْدِ اللَّهِ ۗ وَمَا عِنْدَ اللَّهِ خَيْرٌ لِلْأَبْرَارِ
Sugbon awon t’o beru Oluwa won, awon Ogba Idera ti awon odo n san ni isale re n be fun won. Olusegbere ni won ninu re. Ibudesi kan ni lati odo Allahu. Ohun ti n be lodo Allahu si loore julo fun awon eni rere
وَإِنَّ مِنْ أَهْلِ الْكِتَابِ لَمَنْ يُؤْمِنُ بِاللَّهِ وَمَا أُنْزِلَ إِلَيْكُمْ وَمَا أُنْزِلَ إِلَيْهِمْ خَاشِعِينَ لِلَّهِ لَا يَشْتَرُونَ بِآيَاتِ اللَّهِ ثَمَنًا قَلِيلًا ۗ أُولَٰئِكَ لَهُمْ أَجْرُهُمْ عِنْدَ رَبِّهِمْ ۗ إِنَّ اللَّهَ سَرِيعُ الْحِسَابِ
Dajudaju o n be ninu awon ahlul-kitab eni t’o gbagbo ninu Allahu, ati ohun ti A sokale fun yin ati ohun ti A sokale fun won; won n paya Allahu, won ki i ta awon oro Allahu ni owo kekere. Awon wonyen ni esan lodo Oluwa won. Dajudaju Allahu ni Oluyara nibi isiro-ise
يَا أَيُّهَا الَّذِينَ آمَنُوا اصْبِرُوا وَصَابِرُوا وَرَابِطُوا وَاتَّقُوا اللَّهَ لَعَلَّكُمْ تُفْلِحُونَ
Eyin ti e gbagbo ni ododo, e se suuru, e parowa suuru, e so bode ilu yin (lati le dena awon omo-ogun ota esin). Ki e si beru Allahu nitori ki e le jere

Choose other languages: